E ba wa dele E mo nipa wa ba wa sise Adiresi wa E polowo oja yin AKEDE Agbaye Idanileko ALAROYE Shuaibu Amodu: Nibo ni Eagles n lo? Taofik Afolabi ati Soyemi Oluyinka L Bi o ba fe Awon Iroyin to se koko Fayemi lo l'Ekiti, Fayose de ati O·joôboô, Toôsde, oôseô to koôja ti ajoô ere boôoôlu ileô yii, NFF, ti yoô Koosôi Super Eagles, Stephen Keshi, ti woôn si fi Shuaibu Amodu roôpo reô ni orisôiirisôii oôroô ti n jeôyoô. Nisôe ni inu awoôn kan n dun pe nnkan tawoôn feô lo sôeôleô, tawoôn mi-in si n binu si NFF pe ajoô awoôn ti ko larojinleô ni. Ohun tawoôn toôroô naa dun moô ninu n soô ni pe asôeju Keshi ti poô ju, nisôe lo n sôe bii eôni pe oun ni oôba Super Eagles, ati pe oun le mu agbaboôoôlu to ba wu oun. Woôn ni gbogbo bi oôroô yii sôe n loô lo yeô ko ti moô pe woôn yoo le oun danu, o si yeô ko koôwe fipo sileô, sôugboôn owo to n gba ti woô oô loju. Ni bayii ti oju reô ti ja a, asôeteô loôroô reô ja si. Sôugboôn awoôn mi-in ni oôroô ko ri beôôeô rara, koosôi to ni laakaye ni Keshi, gbogbo awoôn oôta lo si pa leônumoô nigba to gba ife-eôyeô ileô Afrika loôdun to koôja. Woôn ni awoôn oôta eô ninu ajoô NFF lo wa isôubu reô, awoôn lo jeô ko da bii alagidi, bi woôn si sôe yoô oô yii, wahala ti ba Eagles. Nigba ti Keshi funra reô n soôroô loôseô to koôja, oôkunrin eôni oôdun mejilelaaadoôta oôhun soô pe inu oun ko bajeô, oun si dupeô loôwoô awoôn agbaboôoôlu ati NFF to fun oun lanfaani lati sôisôeô koosôi Naijiria. O ni, "Mo dupeô loôwoô awoôn agbaboôoôlu, ajoô NFF ati gbogbo oômoô Naijiria fun oôroô iyanju ati eebu ti woôn fi ransôeô si mi. Eagles ki i sôe oye idile eônikeôni, inu mi si dun pe mo sôe iwoôn ti mo le sôe. Shuaibu Amodu to sôeôsôeô gba isôeô naa jeô oôreô mi gidi, beôeô lo da mi loju pe yoo sôisôeô takuntakun. "Awoôn kan lo n fa oôwoô aago Eagles seôyin nitori pe woôn ko feôran mi. Mo ti moô pe ohunkohun lo le sôeôleô si mi ko too di akoko yii, sôugboôn ohun to dun mi ju ni pe mi o pari awoôn nnkan kan ti mo beôreô." Osôu koôkanla, oôdun 2011, ni Stephen Keshi di koosôi Super Eagles. O gba ife-eôyeô ileô Afrika loôdun to koôja, beôeô lo gba ami-eôyeô koosôi to dangajia ju loôdun kan naa. Shuaibu Amoôdu to jeô koosôi Eagles tuntun gba boôoôlu fun Kiloôoôbu Dumez ati Niger Tornadoes, sôugboôn ifarapa to ni lo gba isôeô naa loôwoô reô. O sôe koosôi fun eôgbeô agbaboôoôlu bii meôrin ko too di koosôi ileô wa. O koôkoô sôe e loôdun 2001 si 2002, o si pada wa ni 2008 si 2010. Shuaibu Amodu ni koosôi Eagles tuntun bayii, awoôn ololufeô boôoôlu si n worere aye eôgbeô naa, beôeô ni woôn n beere pe njeô oôkunrin naa ni Messiah ti Eagles nilo bi.? Wahala sele ninu egbe APC l'Osun Wahala nile igbimo asofin Ekiti Ibo gomina odun to n bo: Awon Egba gbe Sarafa Isola dide lati koju Amosun O n rugbo bo! Ife ati Modakeke tun fee gbena woju ara won Pius ati ololufe e ti won ji omo araale won gbe ni Olodi-Apapa ti dero kootu E tun pade wa lori ero E wa awon iroyin wa
© Copyright 2025