Boya Naijiria yoo ri mi bayii—Sanni Issa - ALAROYE

E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
Boya Naijiria yoo ri mi bayii—Sanni Issa
Awuyewuye n waye
O
moôkunrin eôni oôdun meôtalelogun to n sôe beôbeô fun Kiloôoôbu Auckland, lorileô-ede New
Zealand, Sanni Issa, ti soôroô bayii pe o wu oun lati gba boôoôlu fun Naijiria, boya asiko si ti to
tawoôn eeyan yoo moô oun.
O·roô iwuri yii lo soô nigba to gba boôoôlu to mu eôgbeô reô gbegba oroke nibi ifeseôwoônseô idije
kiloobu iha Asia ati Afrika, eyi to mu woôn wa ni ipo keôta fun igba akoôkoô. Eôgbeô agbaboôoôlu reô
ati Cruz Azul lo koju ara woôn loôseô to koôja, nigba ti ayo si maa pari, ayo koôoôkan ni woôn ni.
O·roô di oôroô peônariti, ko si deôrun fawoôn ikoô mejeeji rara.
Nigba ti woôn gba a loô gba a boô, o kan
Issa, eôru si n ba gbogbo eeyan. Bo sôe gba boôoôlu naa bayii, Jose Corona ti i sôe amule Cruz
Azul ko le mu un rara, oôwoô reô o tieô sunmoô oôn. Bayii ni ariwo soô, idunnu sôubu layoô fun
Auckland, beôeô lawoôn ololufeô woôn ko le pa oôroô naa moôra rara.
Issa funra reô ko moô nnkan to le soô, sôugboôn oôroô to wa seônu reô ni pe boya asiko ti to ti awoôn
alasôeô ere boôoôlu Naijiria yoo ri oun, nitori o wu oun lati inu wa lati sôe beôbeô fun orileô-ede yii,
sôugboôn ko seôni to wo oun rara. O ni asôeyoôri toun sôe yii wu oun lori koôja sisoô, o si ti to akoko
tawoôn eeyan yoo maa gboô orukoô oun.
Nnkan ko deôrun fun oômoôkunrin yii rara lati ibeôreô isôeô boôoôlu gbigba. O·dun 2011 lo darapoô moô
Suva FC nileô Fiji, ibeô lo si gba de Ba Football Association lorileô-ede kan naa. O·dun 2013 ni
woôn sôe ofin kan pe ajoji ko gboôdoô gba boôoôlu ni awoôn kiloôoôbu nla ilu oôhun, bo sôe fi ibeô sileô
niyeôn.
O loô si Amicale FC lorileô-ede Vanuatu, beôeô lo gba Kiloôoôbu Waikato FC loô nibeôreô oôdun yii.
Sôugboôn wahala mi-in tun sôeôleô, oôroô fisa di isôoro fun un, ko si gba boôoôlu fun woôn rara. Nigba
ti iyanu maa sôeôleô, Koosôi Auckland, Ramon Tribulietx, pe e, o si sôeôsôeô darapoô moô woôn laipeô
yii ni. Sôugboôn beôbeô to sôe fun woôn yii ti mu un di olokiki lorileô-ede naa, beôeô lawoôn to moô
nipa boôoôlu n soô pe ogo reô yoo tuboô buyoô nitori o joô pe asiko reô ti to.
lori ibo abele PDP ni
Kwara
L’Ogbomoso, ode
yinbon pa Iya Ayo ni
soosi lojo ikore
Oro ti beyin yo fun
Mimiko, ile-ejo fagile
awon oloye to yan ninu
egbe PDP l'Ondo
Awon ara Arigidi
Akoko ni kijoba ma fiya
ona meji je T.B Joshua
Ile-ejo da Fayose lare
l'Ekiti, lawon araalu ba
n yo sese
E ma se gbiyanju lati yi
ibo odun to n bo—
Kumuyi
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa