Ribery gboriyin nla fun David Alaba

E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Ribery gboriyin nla fun David Alaba
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
O
Eewo! Jega ko tun
oômoô ileô Naijiria to n sôe beôbeô lorileô-ede Austria ati Germany, David Alaba, ki i sôe agbaboôoôlu
to sôe e foôwoô roô seôyin rara. O soôroô oôhun peôlu idaniloju lopin oôseô to koôja leôyin beôbeô ti David
sôe lori awoôn ayo kan to n gba woôle leônu oôjoô meôta yii.
Firi kiiki (free kick) ti David ju woôle l’O·joôru, Weôsde, to koôja nigba ti Kiloôoôbu Bayern
Munich toun ati Ribery wa koju eôgbeô agbaboôoôlu Eintracht Braunschweig jeô oôkan ninu awoôn
to gba woôle ninu ifeôseôwoônseô meôta to gba gbeôyin. Osôu to koôja lo sôe beôbeô manigbagbe kan
nigba ti woôn koju Stuttgart, iyeôn lasiko ti ireti ti feôeô pin.
Gbogbo eyi lo mu Ribery soô pe ko seôni to le gba iru boôoôlu ti David gba woôle loôseô to koôja
yeôn. O ni oômoôkunrin eôni oôdun mejilelogun oôhun n gbiyanju si i lojoojumoô, ibi to si n ba oôroô
reô loô, okiki reô yoo kan fun igba pipeô.
Oôdun 2008 ni David baleô si Bayern Munich II, iyeôn ipele kekere, 2010 lo si de ipele to wa
yii. Orileô-ede Austria lo n gba boôoôlu fun nitori ibeô ni woôn bi i si. O·moô orileô-ede Phillipines
ni iya reô, Yoruba ni baba reô, David O·latokunboô Alaba ni woôn si soô oô.
O fitan baleô ni Austria geôgeô bii agbaboôoôlu to kere ju ninu ikoô awoôn agba loôdun 2009, nigba
to jeô oômoô oôdun meôtadinlogun. Di akoko yii, o wa lara awoôn agbaboôoôlu orileô-ede oôhun to
lokiki ju lagbaaye, beôeô lo ti gba orisôiirisôii awoôoôdu nibeô, lara reôni agbaboôoôlu to dangajia ju
loôdun 2011, 2012, 2013 ati 2014.
siwaju mo o
lokiki agbaboôoôlu agbaye lati ileô France nni, Franck Ribery, ti ju oôroô sigboro bayii pe
gbodo sun ojo idibo yii
Awon ologun ko ni i
faaye gba ojusaaju
lakooko idibo l'Oke
Ogun
Ipo oba da wahala sile
n’Ido-Ani, lawon
omooba ba lura won
lalubami
Aare Jonathan sabewo
si Owa Obokun lle Ijesa
Dokita ati looya e wo
gau, riba ni won fee fun
EFCC
Oloselu to ba koja aaye
re yoo sewon—
Igbakeji oga olopaa
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa