Alaboyun ku si osibitu Celestine, ayederu dokita, l`Ekoo

E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi w
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
Alaboyun ku si osibitu Celestine, ayederu
dokita, l’Ekoo
Isegun ni pasito loun
A
Egbe PDP Osun da
yederu dokita eôni oôdun moôkandinlogoji kan, Yonlonfun Celestine, loôwoô awoôn oôloôpaa
ti teô leôyin ti obinrin alaboyun kan ku si oôsibitu reô, ‘Be Well Hospital’, to wa lagbegbe
Tomaro, Apapa, niluu Eko. Oun la gboô pe o jeô alasôeô ati oludasileô ibeô.
Geôgeô bi ALAROYE sôe gboô, obinrin alaboyun kan loôkoô reô gbe loô si oôsibitu oôhun sôugboôn to
ku sibeô, nigba tawoôn oôloôpaa si da soôroô naa ni woôn ri i pe ayederu ni eôni to ni ibeô, ko tieô kawe
pari isôeô to joô moô iwosan to fi da oôsibitu sileô. Geôge bi alaye ti CP Fatai Owosôeni, koômisôanna
oôloôpaa ipinleô Eko sôe fakoôroyin wa, eôgbeô awoôn dokita nileô yii, “Medical and Dental Council
of Nigeria’’ (MDCN), ti soô pe awoôn ko moô Celestine ri, woôn ni ki i sôe ara awoôn, ati pe
satifikeeti Fasiti Ibadan to n gbe kiri ki i sôe ojulowo.
Nigba ta a beere oôroô loôwoô Celestine, ko jiyan rara, o ni bi woôn sôe soô oô yeôn naa lo ri. Geôgeô bo
sôe soô, “ Loootoô ni pe mi o ki n sôe ojulowo dokita. Ipele keôta ileewe girama (JSS3) ni mo wa
ti moô ti sa nileewe, leôyin igba yeôn ni mo gba orileô-ede Benin loô. Nigba to di 2003, mo loô si
ileewe eôkoôsôeô noôoôsi kan nibeô, sôugboôn mi o tun pari, bi mo sôe pada si Naijiria niyeôn loôdun
2004.
“Lati kekere lo ti wu mi lati jeô dokita, idi ti mo fi n sôe gbogbo akitiyan yeôn niyeôn. Nigba ti
mo pada de ni mo wa yara kan ti mo beôreô isôeô iwosan tawoôn eeyan si n wa, sôugboôn leôyin
oôdun kan ni mo waa beôreô isôeô geôgeô bii dokita. Loôdun 2015, mo koô ile iwosan temi, lati igba
naa ni mo si ti beôreô isôeô ni peôreôu. Gbogbo awoôn eeyan agbegbe yeôn lo moô mi daadaa, woôn si
maa n wa. Ko si eôni ti mi o ki n toôju, to fi dori awoôn alaboyun titi ti woôn fi maa bimoô. Isôeô ti
mo ba moô pe mi o le sôe, mo maa ni ki woôn loô si oôsibitu mi-in ti mo ba soô fun woôn ni.
“Obinrin kan to ku si oôsibitu mi toyuntoyun lo koba mi nitori o ni aisan giri lara. Bi oôkoô eô sôe
gbe e de ni mo ti ni ko maa loô sibomi-in, sôugboôn sôe lo n beô mi titi ti mo fi gba. Igba tiyawo eô
ku tan ni wahala de. Keô eô deô maa wo o, awoôn meji pere lo ku soôdoô mi latoôjoô ti mo ti beôreô.”
Ileesôeô oôloôpaa ti waa ti ile iwosan naa pa bayii, iwadii si n loô loôwoô lati moô awoôn nnkan mi-in
nipa oôkunrin ayederu dokita oôhun. Geôgeô bi a sôe gboô, laipeô ni Celestine yoo foju bale-eôjoô.
fee se fun Dolapo, lo ba
fipa ba a lo po
Omisore ati Wale
Oladipo duro
Ogunlewe ati oga-agba
FUNNAB ko reni gba
beeli won
Eto tuntun ti yoo ropo
gbale-gbata olosoosu
yoo bere laipe
Tunde lu tisa lalubami
n’Ilorin, o ni esan
aburo oun loun gba
Deborah gbe iya iyawo
ati iyawo omo e lo si
kootu
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa