Todo está listo para la fiesta democrática

E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Shuaibu Amodu: Nibo ni Eagles n lo?
Taofik Afolabi ati Soyemi Oluyinka
L
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
Fayemi lo l'Ekiti,
Fayose de
ati O·joôboô, Toôsde, oôseô to koôja ti ajoô ere boôoôlu ileô yii, NFF, ti yoô Koosôi Super Eagles,
Stephen Keshi, ti woôn si fi Shuaibu Amodu roôpo reô ni orisôiirisôii oôroô ti n jeôyoô.
Nisôe ni inu awoôn kan n dun pe nnkan tawoôn feô lo sôeôleô, tawoôn mi-in si n binu si NFF pe ajoô
awoôn ti ko larojinleô ni.
Ohun tawoôn toôroô naa dun moô ninu n soô ni pe asôeju Keshi ti poô ju, nisôe lo n sôe bii eôni pe oun
ni oôba Super Eagles, ati pe oun le mu agbaboôoôlu to ba wu oun. Woôn ni gbogbo bi oôroô yii sôe
n loô lo yeô ko ti moô pe woôn yoo le oun danu, o si yeô ko koôwe fipo sileô, sôugboôn owo to n gba ti
woô oô loju. Ni bayii ti oju reô ti ja a, asôeteô loôroô reô ja si.
Sôugboôn awoôn mi-in ni oôroô ko ri beôôeô rara, koosôi to ni laakaye ni Keshi, gbogbo awoôn oôta lo
si pa leônumoô nigba to gba ife-eôyeô ileô Afrika loôdun to koôja. Woôn ni awoôn oôta eô ninu ajoô NFF
lo wa isôubu reô, awoôn lo jeô ko da bii alagidi, bi woôn si sôe yoô oô yii, wahala ti ba Eagles.
Nigba ti Keshi funra reô n soôroô loôseô to koôja, oôkunrin eôni oôdun mejilelaaadoôta oôhun soô pe inu
oun ko bajeô, oun si dupeô loôwoô awoôn agbaboôoôlu ati NFF to fun oun lanfaani lati sôisôeô koosôi
Naijiria.
O ni, "Mo dupeô loôwoô awoôn agbaboôoôlu, ajoô NFF ati gbogbo oômoô Naijiria fun oôroô iyanju ati
eebu ti woôn fi ransôeô si mi. Eagles ki i sôe oye idile eônikeôni, inu mi si dun pe mo sôe iwoôn ti mo
le sôe. Shuaibu Amodu to sôeôsôeô gba isôeô naa jeô oôreô mi gidi, beôeô lo da mi loju pe yoo sôisôeô
takuntakun.
"Awoôn kan lo n fa oôwoô aago Eagles seôyin nitori pe woôn ko feôran mi. Mo ti moô pe
ohunkohun lo le sôeôleô si mi ko too di akoko yii, sôugboôn ohun to dun mi ju ni pe mi o pari
awoôn nnkan kan ti mo beôreô."
Osôu koôkanla, oôdun 2011, ni Stephen Keshi di koosôi Super Eagles. O gba ife-eôyeô ileô Afrika
loôdun to koôja, beôeô lo gba ami-eôyeô koosôi to dangajia ju loôdun kan naa.
Shuaibu Amoôdu to jeô koosôi Eagles tuntun gba boôoôlu fun Kiloôoôbu Dumez ati Niger
Tornadoes, sôugboôn ifarapa to ni lo gba isôeô naa loôwoô reô. O sôe koosôi fun eôgbeô agbaboôoôlu bii
meôrin ko too di koosôi ileô wa. O koôkoô sôe e loôdun 2001 si 2002, o si pada wa ni 2008 si 2010.
Shuaibu Amodu ni koosôi Eagles tuntun bayii, awoôn ololufeô boôoôlu si n worere aye eôgbeô naa,
beôeô ni woôn n beere pe njeô oôkunrin naa ni Messiah ti Eagles nilo bi.?
Wahala sele ninu egbe
APC l'Osun
Wahala nile igbimo
asofin Ekiti
Ibo gomina odun to n
bo: Awon Egba gbe
Sarafa Isola dide lati
koju Amosun
O n rugbo bo! Ife ati
Modakeke tun fee
gbena woju ara won
Pius ati ololufe e ti won
ji omo araale won gbe
ni Olodi-Apapa ti dero
kootu
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa